Ẹ̀rọ Àyẹ̀wò Ilé Ọmọ
Ó ti tó ìgbàwo tí o ti lóyún? Ìwádìí fi hàn pé ìsẹ́yún ni ìlànà ìlera jẹ ọ̀kan gbòógì nínú ìgbani níyànjú fún oyún ṣáájú oṣù mẹ́tàlá sígbà tí o bá ṣe ǹ kan oṣù. Lo ẹ̀rọ àyẹ̀wò ilé ọmọ láti mọ òṣùwọ̀n ìgbà tí oti lóyún sí ìgbà tí o ṣe nkan oṣù gbẹ̀yìn.
Tí nkan oṣù rẹ bá bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ tàbí lẹ́yìn:
21 Oṣù Ọ̀wàrà 2024
O sì le gbìyànjú láti lo àwọn ògùn ìsẹ́yún.
Ṣé oyún rẹ ti kọjá ọ̀sẹ̀ méjìlá?
Àwọn ìlànà tí HowToUseAbortionPi wà fún àwọn tí oyún wọn wà láàrin ọ̀sẹ̀ 13. Síbẹ̀, o sì le lo àwọn ògùn ìsẹ́yún tó bá yá pẹ̀lú ìlànà míràn.
Fún àlàyé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́, ẹ lè kàn sí àwọn ọrẹ wa lórí www.womenonweb.org tàbí kí ẹ lọ sí orí profili orílẹ̀ èdè wa láti mọ si nípa àwọn ohun èlò ìsẹ́yún ní orílè-èdè rẹ.
Àwọn ohun àmúyẹ kí o tó lè lo ògùn ìsẹ́yún
Ìmọ̀ràn Àpapọ̀
Ṣíṣe Ètò Ààbò
Bí àjọ World Health Organization(WHO) ti wí, àwọn ògùn ìsẹ́yún kò mú ewu dání tí ìjàmbá kò sì wọ́pọ̀. Síbẹ̀ síbẹ̀, ó dára láti gbáradì tí nkan bá fẹ́ yíwọ́. O lè lo àwọn ìbéèrè yìí láti ṣe ètò ààbò rẹ tí o bá nílò rẹ.
Itọkasi:
- “Induced Abortion.” American College of Obstetrics and Gynecologists. https://www.acog.org/Patients/FAQs/Induced-Abortion
- “Care for Women Choosing Medication Abortion.” The Nurse Practitioner. https://journals.lww.com/tnpj/Citation/2004/10000/Care_for_Women_Choosing_Medication_Abortion.9.aspx
- “Safe abortion: technical and policy guidance for health systems.”The World Health Organization. https://apps.who.int/iris/bitstream/handle/10665/70914/?sequence=1