HowToUseAbortionPill (Àwa tàbí ilẹ iṣẹ wa) je ilé isẹ to ni ètò ayélujára àti èrò ayarabiasa lati mu ki awọn ènìyàn kakiri ayé ni ẹ̀kọ́ imọ to péye lori bi ase le lo òògùn oyún ṣíṣẹ́, tó sì má jé kí wọn ni òògùn oyún ṣíṣẹ́ ni gba kugba ti wọn ba fẹ́ (sístẹ̀mù wa). Awọn ètò yi gba àmì ìdámò oni kálukú (PII) nípa ẹni tí lo, ati pẹlu awọn oṣiṣẹ ile iṣẹ, awọn oṣiṣẹ ti sise lati ile, ati tàwọn ti wa iṣẹ (Oṣiṣẹ). Eto asiri ibi ipamọ ma so nipa iru awon ida ni mo ti a gba àti ẹtọ àwọn tí lo wọn awọn idanimọ yìí. Nigbati a ba se ètò ìṣàkóso lori àwọn sistemu, awọn oṣiṣẹ ita yo fún yi ni awọn eto miran lati le je ki lílo rẹ lọ dáadáa.
A dá ètò àṣírí ibi ipamọ lati lè dáàbò bo Ìdánimọ̀ àwọn tí n lo.
A ní ètò lati se àtúnṣe sí ètò àṣírí ibí ìpamọ́ yí ni ọjọ iwájú. A ò ní fi tó àwọn oníbárà wa ni eti ti atunṣe ohun kò bá ni mu ìpalára wà fún ètò ipamọ wọn – bi se se àtúnṣe lati mu ki ètò àṣírí ibi ipamọ yi tun dára si, tàbí ti tun awọn ọrọ ti a ko ko dada tẹ́lẹ̀ se, tàbí ṣíṣe àfikún ọrọ. Fún àwọn àtúnṣe tí ọ yẹ ki awon olubara wa mo, a ma fi atejise ránṣẹ́ sí wọn lórí ẹrọ ímeèlì wọn. Ti a ko ba ni ero ímeèlì awon oníbárà kan tabi meji, kò ni sí bí a ṣe ma fi atejise ranṣẹ sí wọn ti a ba se àwọn àtúnṣe won yi. A lè ṣe awọn àfikún tabi àtúnṣe yi ni pa dídá eto ayelujara miran tabi ibaraẹnisọrọ.
A lè fi àtúnṣe sí ètò àṣírí ipamọ yi sí orí ètò ayélujára wa tàbí ki a fi ìwé ohùn se atejise sí ọ.
Ètò àṣírí ibi ipamọ wa kò ni ajọṣepọ kan kan pẹ̀lú àwọn àyè ayélujára ti ẹni kẹta lati sístẹ̀mù wa. A ọ ni ibamu sí lilọ, ayẹwo, tàbí ètò àṣírí ibi ipamọ iru aye ayelujara ẹni kẹta bẹ. Awọn eto ti ọ ba wa lori iru aye ayélujára owun ma wa lábé àbò ètò àṣírí ibi ipamọ, ọrọ ati eto ibi ipamọ ti ayé ayélujára yẹn. A ma gba e ni ìyànjú lati ri pe ọ ka won.
Àwọn Ohun Ìdánimọ̀ Tí a Ma Gbà
Nínú ètò àṣírí ibi ipamọ wa, gbogbo àwọn ọrọ idanimọ ti a ma gbà ni a ma pe ni PII. A ma ko àwọn idanimọ yi jo lati odo gbongbo àwọn oníbárà wa, tí yíò fi iru oníbárà ti ọ ba je hàn. Àwọn ọrọ ohun ni.
Gbígba Àlàyé Nípa Rẹ.
A má gba àyè ki a to gba PII. Nípa ibaraenisoro pẹlú sístẹ̀mù, àwọn onibara wa ni lati fun wa ni ayé ni ibamu pẹlú (1) àwọn òfin ètò àṣírí ibi ipamọ ati (2) fún àkójọ, lilọ ati ìdídá dúró àwọn àlàyé ti e ti fún wa wọ̀nyí àti èyí ti sístẹ̀mù gbà fún lílò ọna ẹrọ.
Ní ọ̀nà míràn ẹ̀wẹ̀, nígbàkúùgbà ti onibara ba ni Ìbánisọ̀rọ̀ pẹlú sístẹ̀mù, o ma gbà PII lati owo one ẹrọ ti onibara ba lo ti yi ọ sí gbà PII ti onibara ba fún ni àsìkò Ìbánisọ̀rọ̀ pẹlú sístẹ̀mù.
Ọnà àti Gba Àlàyé Nípa Ara Ẹ̀ni.
Gbogbo ìgbà ni a má wa ọna ti ọ sunwọn ti ọ sí ṣe dáradára láti se àkójọpọ̀ PII, àti àwọn ọnà míràn tí a lè se àtúnṣe lori àwọn òfin ètò àṣírí
A ma lo àwọn PII ti a gba ni àwọn ọ̀nà báyìí
A máa gbé ìgbésẹ̀ to ni túmọ̀ to si leto lábé òfin lati lè yẹra fún fifi tipátipá tu PII lati odo àwọn oṣiṣẹ ìjọba kankan tàbí ẹni kẹta tọ ọ ba ni ànfàní sí. Nigba miran, awọn oṣiṣẹ ijoba ati/tabi eni-keta le ni aṣẹ labẹ ofin lati je ki iru ile iṣẹ wa ti awọn PII, ni iru àwọn ìgbà ba yìí, ọ di dandan ki a se bẹ
Irú àwọn PII ti àwọn oṣiṣẹ bi eni keta ba gba ati/tabi fi pamo nípa si ṣiṣe sinu sístẹ̀mù, awa ko ni ipa lori lilọ ati/tàbí ipamọ iru PII yen.
Bi a ṣe ṣàlàyé ni apá ètò, àṣírí ibi ipamo ti a pe àkọlé rẹ ní “ÈTÒ RẸ LORI ÀLÀYÉ ÌDÁNIMỌ̀ RẸ”, ọ ni ẹtọ lati se bó bá ṣe wún ọ pẹlu PII gege bi a se salaye ni apa yen.
Ètò Rẹ Lórí Àlàyé Ìdánimọ̀ Rẹ
Àwọn ètò oníbárà wa nipa PII ni àwọn wọn yìí:
Lati lè lo agbára lori awọn eto yi, oníbárà ni lati pèsè ímeèlì adiresi ti ọ kun oju osunwon ati lati tẹle awọn ilana ti a ti fi sí isale ni bi apa eto asiri ibi ipamo ti a pe àkọlé rẹ ní “BI Ẹ SE LE BA WA SỌ̀RỌ̀ PẸ̀LÚ AWỌN IBẸRẸ, AFIKUN TABI AWON ORO YIN”. Ti oníbárà kan ko ba fún wa ni ímeèlì adiresi to kun oju osunwon, a wa ko ni ni afani lati lè bá iru eni bẹ soro: eyi sí fa idena sí (1) fifi ate ranṣẹ sí wọn ni pa àwọn àtúnṣe ti a se sí eto ibi ipamọ ati awọn ohun tó lè su yọ nipa PII won (2) ati ki a le se ayẹwo nipa idanimo won ki a ba le je ki won se eto won bo se tọ àti bí o se ye, se àtúnṣe, wa ni ipa won tabi parẹ PII won rẹ.
Àwa kì í gba idanimo àwọn ènìyàn lati omodun mẹtala sí ìsàlẹ̀. Nigba ti sístẹ̀mù wa ki se fún àwọn ọmọdé , ti a ko si se iwadi lẹkunrẹrẹ nipa ọjọ ori àwọn oníbárà wa, a le se sí gbà PII ti omode ti ọ ba lo sístẹ̀mù wa. O se de bi or awon oníbárà wa ma fi PII awọn eniyan ti ojo ori won jẹ́ ọmọ ọdún metala, ti ile iṣẹ waa yìo sì tọjú iru PII wa gẹgẹ bẹ ètò àṣírí ibi ìpamọ́, wa. Ti a ba mọmọ ni ibanisoro pẹlu ọmọ ọdún mẹtala, a o ni ki iru eniyan bẹ gba ayé lodo awon obi ki won to le bá sístẹ̀mù soro.
Láti dabobo PII rẹ, ọ gbọdọ ṣe àwọn igbesẹ iwọnyi;
Àwa kì í topi pin ènìyàn nípasẹ̀ ayé ayélujára ti ènìyàn kẹta lati se ìpolówó. Nítorí náà, àwa ko ni dáhùn sí ẹrọ itopinpin (DNT)
Bí Ẹ Se Le Bá Wa Sọ̀rọ̀ Lórí Àwọn Ìbéèrè, Idasi Tàbí Àwọn Ohun Ti E Fẹ́:
Fún ìbéèrè, Idasi tàbí àwọn ohun ti e fẹ́ ẹ kan sí wa lórí info@howtouseabortionpill.org. Àwa na máa se ìwádìí ènìyàn ti o ba lo ímeèlì ti ko ba sì lọdọ wa ka to ba irú ẹni bẹ sọ̀rọ̀ nípa PII
Bí a se sọ síwájú, tí o ko ba fún wa ní ímeèlì adiresi ti o yanjú ni gba ti o ba kókó ba wa sọ̀rọ̀, tàbí nígbà tí o fún wa ni PII, àwa kò ni le ṣe ìwádìí tó péye lori ẹni náà ti èyí yíò sì fa ìdènà lati jẹ́ ki a gba ki irú ẹni bẹ se ètò lori PII tí o ba wa ni àrọ́wọ́tó wa.
Ọ̀rọ̀ Tí Ó Parí:
Ètò àṣírí ibi ìpamọ́ yìí jẹ èyí ti a se àtúnṣe rẹ ni oṣù kejì, ọjọ kẹrìnlélógún odun 2024. A o sì tún ṣe àtúnṣe sí ètò àṣírí ibi ìpamọ́ yi ni ekan láàrin oṣù méjìlá.