Rárá, iye òògùn kan náà ni gbogbo ènìyàn máa lo. Ìwádìí fi hàn pé iṣẹ́ òògùn náà ò kan bí èèyàn bá ṣe tóbi tó. O kò nílò òògùn púpọ̀ tàbí ìlànà mìíràn.
Àwọn Ìbéèrè Oyún ṣíṣẹ́ – Òògùn Ìsẹ́yún FAQs
Ta Ni Ó Lè Lo Òògùn Ìsẹ́yún?
- “Abortion Explained! Queer & Trans Justice.” We Testify. https://www.wetestify.org/abortion-explained-queer-trans-justice
- “Drug interaction tool.” UpToDate. https://www.uptodate.com/login
O kò nílò láti pààrọ̀ iye òògùn tí o bá mọ̀ pé o lóyún ìbejì. Ìlànà ogún kan náà ni ó wà fún oyún ìbejì bí ó ti wà fún oyún ọkan.
Rárá, oyún kọ̀ọ̀kan yàtọ̀ gédégbé sí ara wọn. Kódà kí o ti lò àwọn òògùn ìsẹ́yún rí, nǹkan tí o lò ní àkọ́kọ́ náà ni ó máa lò fún oyún mìíràn tí o fẹ́ ṣẹ́.
Tí ẹ̀rọ ìdènà oyún nínú ojú ara rẹ (fún àpẹẹrẹ, èyí tí wọ́n kọpa tàbí èyí tí ó ní hòmóònù “progesterone” IUD) A gbà ọ níyànjú pé kí o yọ ọ́ kí o tó lo àwọn ògùn ìsẹ́yún náà.
O le fún ọmọ lọ́mú ní àsìkò tí ò bá ń lo àwọn ògùn ìsẹ́yún. Mifepristone àti Misoprostol má ń wọnú ọyàn ní ìwọ̀n kékeré, ìwọ̀n yìí kò sì le fa ìjàmbá fún ọmọ náà. Fífún ọmọ lọ yàn leè tẹ̀síwájú láì sí ìdádúró lásìkò lílo àwọn ògùn ìsẹ́yún
Tí o bá ní HIV, o sì le lo àwọn ògùn ìsẹ́yún bíi àwọn ẹlòmíràn. Ríi dájú pé o sì ń lo òògùn tí ó ń gbógun ti kòkòrò àìfojúrí HIV (antiretroviral) kí o sì wà ní ìlera.
Tí o bá ní anémíà (àìtó áyọ́ọ̀nù nínú ẹ̀jẹ̀), o sì le se ìsẹ́yún nípa ògùn ṣùgbọ́n wá elétò ìlera tí ọ̀dọ̀ rẹ̀ ò jìnà ju ọgbọ̀n ìṣẹ́jú sí ọ̀dọ̀ rẹ lọ tí ó sì lè ṣe ìtọ́jú rẹ tí o bá nílò rẹ̀. Tí anémíà rẹ bá lè, gba àṣẹ dókítà kí o tó lo òògùn ìṣẹ́yún.
Rárá, kò sí ewu tí ò bá ti ṣẹ́ oyún náà láìpẹ́ tí o ní i kódà kí o ti bímọ pẹ̀lú iṣẹ́ abẹ rí.
Kò tíì sí àsopọ̀ láàrín mifepristone àti àbùkù ara ọmọ ṣùgbọ́n misoprostol lè mú u ṣẹlẹ̀. Tí o bá lo misoprostol tí oyún náà sì wà lára rẹ, ó ṣeéṣe kí oyún náà wálẹ̀ fúnraàrẹ. Tí oyún náà ò bá sì wálẹ̀ títí àkókò ìbí fi tó, ewu fún oyún inú látàrí misoprostol kò tó ìwọ̀n mewa 10 nínú 1000
Tí o bá dènà oyún tí o sì ti wá lóyún, o sì le lo àwọn ògùn ìsẹ́yún. Ṣùgbọ́n o léwu ju àwọn akẹgbẹ́ rẹ lọ tí oyún tí ó ń dàgbà lẹ́yìn ilé ọmọ látàrí ìdènà oyún tí o ṣe. O le pinnu láti tẹ̀síwájú pẹ̀lú lílo àwọn ògùn ìsẹ́yún ṣùgbọ́n tí oyún náà bá wà lẹ́yìn ilé ọmọ, ògùn náà kò ní ṣíṣẹ́. Kò sí ewu àmọ́ oyún tí ó wà lẹ́yìn ilé ọmọ yío sì máa dàgbà tí èyí sì ní ewu. Tí oyún náà bá wà lẹ́yìn ilé ọmọ yío nílò ayẹwo ọ̀tọ̀ àti ìtọ́jú. Tí o bá tí dènà oyún tí o sì ṣe àyẹ̀wò pé o lóyún (tí kì í ṣe lẹ́yìn ilé ọmọ) kò sí ewu fún lílọ àwọn ògùn ìsẹ́yún.
Tí o bá tí lóyún lẹ́yìn ilé ọmọ rí tí o sì ti ṣe ìtọ́jú ẹ ṣùgbọ́n tí o tún ti wá lóyún, o lè lo àwọn ògùn ìsẹ́yún. Ṣùgbọ́n o léwu ju àwọn akẹgbẹ́ rẹ lọ tí oyún tí ó ń dàgbà lẹ́yìn ilé ọmọ látàrí ìdènà oyún tí o ṣe. O le pinnu láti tẹ̀síwájú pẹ̀lú lílo àwọn ògùn ìsẹ́yún ṣùgbọ́n tí oyún náà bá wà lẹ́yìn ilé ọmọ, ògùn náà kò ní ṣíṣẹ́. Kò sí ewu àmọ́ oyún tí ó wà lẹ́yìn ilé ọmọ yío sì máa dàgbà tí èyí sì ní ewu. Tí oyún náà bá wà lẹ́yìn ilé ọmọ yío nílò ayẹwo ọ̀tọ̀ àti ìtọ́jú. Tí o bá tí dènà oyún tí o sì ṣe àyẹ̀wò pé o lóyún (tí kì í ṣe lẹ́yìn ilé ọmọ) kò sí ewu fún lílọ àwọn ògùn ìsẹ́yún.
Ẹ̀rọ àyẹ̀wò ilé ọmọ là fí ń yẹ Oyún tó ń dàgbà lẹ́yìn ilé ọmọ. Tí o bá tí ṣe àyẹ̀wò pé oyún rẹ ń dàgbà lẹ́yìn ilé ọmọ, a kò gbà ọ níyànjú pé kí o lo àwọn ògùn ìsẹ́yún torí wọn kò ní ṣíṣẹ́. Àmọ́ bẹ dókítà wò fún ìtọ́jú tó péye fún oyún tí o ń dàgbà lẹ́yìn ilé ọmọ. Ní àwọn orílè-èdè tí ayé kò gbà oyún ṣíṣẹ́, wọn leè yà ọ sọ́tọ̀ láti ràn ọ lọ́wọ́.
Gẹgẹ bí ẹni tó ṣe àtúnyàn ìbí tàbí ẹni ti ko ni ìdánimọ̀ ìbí, kò sí ewu tí o bá lo ògùn ìsẹ́yún. Tí o bá ń lo àwọn ògùn homonu ti ọkùnrin, misoprostol tabi mifopristone kò ní dí lọ́wọ́. Òògùn ìsẹ́yún yìí kò ní ewu tí o bá lò ó pẹ̀lú òògùn testosterone (T) àti gonadotrophin ti ọ da homonu (GnRH) àfọwọ́sẹ. Sibẹsibẹ, o lè se alábàápàdé ìjàmbá láti le è lo ètò ìlera oyún ṣíṣẹ́ tó gbá músẹ́. Kọ́ n’ípa ètò oyún ṣíṣẹ́ ni orílè-èdè rẹ.
Àwọn Itọkasi:
Ta Ni Ó Lè Lo Òògùn Ìsẹ́yún?
- “Abortion Explained! Queer & Trans Justice.” We Testify. https://www.wetestify.org/abortion-explained-queer-trans-justice
- “Drug interaction tool.” UpToDate. https://www.uptodate.com/login
Rárá, iye òògùn kan náà ni gbogbo ènìyàn máa lo. Ìwádìí fi hàn pé iṣẹ́ òògùn náà ò kan bí èèyàn bá ṣe tóbi tó. O kò nílò òògùn púpọ̀ tàbí ìlànà mìíràn.
O kò nílò láti pààrọ̀ iye òògùn tí o bá mọ̀ pé o lóyún ìbejì. Ìlànà ogún kan náà ni ó wà fún oyún ìbejì bí ó ti wà fún oyún ọkan.
Rárá, oyún kọ̀ọ̀kan yàtọ̀ gédégbé sí ara wọn. Kódà kí o ti lò àwọn òògùn ìsẹ́yún rí, nǹkan tí o lò ní àkọ́kọ́ náà ni ó máa lò fún oyún mìíràn tí o fẹ́ ṣẹ́.
Tí ẹ̀rọ ìdènà oyún nínú ojú ara rẹ (fún àpẹẹrẹ, èyí tí wọ́n kọpa tàbí èyí tí ó ní hòmóònù “progesterone” IUD) A gbà ọ níyànjú pé kí o yọ ọ́ kí o tó lo àwọn ògùn ìsẹ́yún náà.
O le fún ọmọ lọ́mú ní àsìkò tí ò bá ń lo àwọn ògùn ìsẹ́yún. Mifepristone àti Misoprostol má ń wọnú ọyàn ní ìwọ̀n kékeré, ìwọ̀n yìí kò sì le fa ìjàmbá fún ọmọ náà. Fífún ọmọ lọ yàn leè tẹ̀síwájú láì sí ìdádúró lásìkò lílo àwọn ògùn ìsẹ́yún
Tí o bá ní HIV, o sì le lo àwọn ògùn ìsẹ́yún bíi àwọn ẹlòmíràn. Ríi dájú pé o sì ń lo òògùn tí ó ń gbógun ti kòkòrò àìfojúrí HIV (antiretroviral) kí o sì wà ní ìlera.
Tí o bá ní anémíà (àìtó áyọ́ọ̀nù nínú ẹ̀jẹ̀), o sì le se ìsẹ́yún nípa ògùn ṣùgbọ́n wá elétò ìlera tí ọ̀dọ̀ rẹ̀ ò jìnà ju ọgbọ̀n ìṣẹ́jú sí ọ̀dọ̀ rẹ lọ tí ó sì lè ṣe ìtọ́jú rẹ tí o bá nílò rẹ̀. Tí anémíà rẹ bá lè, gba àṣẹ dókítà kí o tó lo òògùn ìṣẹ́yún.
Rárá, kò sí ewu tí ò bá ti ṣẹ́ oy ún náà láìpẹ́ tí o ní i kódà kí o ti bímọ pẹ̀lú iṣẹ́ abẹ rí.
Kò tíì sí àsopọ̀ láàrín mifepristone àti àbùkù ara ọmọ ṣùgbọ́n misoprostol lè mú u ṣẹlẹ̀. Tí o bá lo misoprostol tí oyún náà sì wà lára rẹ, ó ṣeéṣe kí oyún náà wálẹ̀ fúnraàrẹ. Tí oyún náà ò bá sì wálẹ̀ títí àkókò ìbí fi tó, ewu fún oyún inú látàrí misoprostol kò tó ìwọ̀n mewa 10 nínú 1000
Tí o bá dènà oyún tí o sì ti wá lóyún, o sì le lo àwọn ògùn ìsẹ́yún. Ṣùgbọ́n o léwu ju àwọn akẹgbẹ́ rẹ lọ tí oyún tí ó ń dàgbà lẹ́yìn ilé ọmọ látàrí ìdènà oyún tí o ṣe. O le pinnu láti tẹ̀síwájú pẹ̀lú lílo àwọn ògùn ìsẹ́yún ṣùgbọ́n tí oyún náà bá wà lẹ́yìn ilé ọmọ, ògùn náà kò ní ṣíṣẹ́. Kò sí ewu àmọ́ oyún tí ó wà lẹ́yìn ilé ọmọ yío sì máa dàgbà tí èyí sì ní ewu. Tí oyún náà bá wà lẹ́yìn ilé ọmọ yío nílò ayẹwo ọ̀tọ̀ àti ìtọ́jú. Tí o bá tí dènà oyún tí o sì ṣe àyẹ̀wò pé o lóyún (tí kì í ṣe lẹ́yìn ilé ọmọ) kò sí ewu fún lílọ àwọn ògùn ìsẹ́yún.
Tí o bá tí lóyún lẹ́yìn ilé ọmọ rí tí o sì ti ṣe ìtọ́jú ẹ ṣ ùgbọ́n tí o tún ti wá lóyún, o lè lo àwọn ògùn ìsẹ́yún. Ṣùgbọ́n o léwu ju àwọn akẹgbẹ́ rẹ lọ tí oyún tí ó ń dàgbà lẹ́yìn ilé ọmọ látàrí ìdènà oyún tí o ṣe. O le pinnu láti tẹ̀síwájú pẹ̀lú lílo àwọn ògùn ìsẹ́yún ṣùgbọ́n tí oyún náà bá wà lẹ́yìn ilé ọmọ, ògùn náà kò ní ṣíṣẹ́. Kò sí ewu àmọ́ oyún tí ó wà lẹ́yìn ilé ọmọ yío sì máa dàgbà tí èyí sì ní ewu. Tí oyún náà bá wà lẹ́yìn ilé ọmọ yío nílò ayẹwo ọ̀tọ̀ àti ìtọ́jú. Tí o bá tí dènà oyún tí o sì ṣe àyẹ̀wò pé o lóyún (tí kì í ṣe lẹ́yìn ilé ọmọ) kò sí ewu fún lílọ àwọn ògùn ìsẹ́yún.
Ẹ̀rọ àyẹ̀wò ilé ọmọ là fí ń yẹ Oyún tó ń dàgbà lẹ́yìn ilé ọmọ. Tí o bá tí ṣe àyẹ̀wò pé oyún rẹ ń dàgbà lẹ́yìn ilé ọmọ, a kò gbà ọ níyànjú pé kí o lo àwọn ògùn ìsẹ́yún torí wọn kò ní ṣíṣẹ́. Àmọ́ bẹ dókítà wò fún ìtọ́jú tó péye fún oyún tí o ń dàgbà lẹ́yìn ilé ọmọ. Ní àwọn orílè-èdè tí ayé kò gbà oyún ṣíṣẹ́, wọn leè yà ọ sọ́tọ̀ láti ràn ọ lọ́wọ́.
Gẹgẹ bí ẹni tó ṣe àtúnyàn ìbí tàbí ẹni ti ko ni ìdánimọ̀ ìbí, kò sí ewu tí o bá lo ògùn ìsẹ́yún. Tí o bá ń lo àwọn ògùn homonu ti ọkùnrin, misoprostol tabi mifopristone kò ní dí lọ́wọ́. Òògùn ìsẹ́yún yìí kò ní ewu tí o bá lò ó pẹ̀lú òògùn testosterone (T) àti gonadotrophin ti ọ da homonu (GnRH) àfọwọ́sẹ. Sibẹsibẹ, o lè se alábàápàdé ìjàmbá láti le è lo ètò ìlera oyún ṣíṣẹ́ tó gbá músẹ́. Kọ́ n’ípa ètò oyún ṣíṣẹ́ ni orílè-èdè rẹ.
Àwọn Itọkasi:
Oríṣiríṣi Àwọn Òògùn Ìṣẹ́yún Tí ó Wà Àti Lílò Wọn
- “Induced Abortion.” American College of Obstetrics and Gynecologists. https://www.acog.org/Patients/FAQs/Induced-Abortion
- “Care for Women Choosing Medication Abortion.” The Nurse Practitioner. https://journals.lww.com/tnpj/Citation/2004/10000/Care_for_Women_Choosing_Medication_Abortion.9.aspx
- “Safe abortion: technical and policy guidance for health systems.” The World Health Organization. https://apps.who.int/iris/bitstream/handle/10665/70914/?sequence=1
- “Clinical Updates in Reproductive Health.” Ipas. https://www.ipas.org/clinical-update/english/introduction/
- “Abortion care guideline.” The World Health Organization. https://www.who.int/publications/i/item/9789240039483
Ìwádìí fi hàn pé ìsẹ́yún ni ìlànà ìlera jẹ ọ̀kan gbòógì nínú ìgbani níyànjú fún oyún ṣáájú oṣù mẹ́tàlá sígbà tí o bá ṣe ǹ kan oṣù. Àwọn ìlànà tí HowToUseAbortionPill wà fún àwọn tí oyún wọn wà láàrin ọ̀sẹ̀ 13. A sì le lò ogún ìsẹ́yún fún oyún ti ọ ti jù ìgbà náà ló àmọ́ oríṣiríṣi ìtọ́sọ́nà àti àyẹwò ni a máa wo kí ó ma bà sì ewu. Fún àlàyé lẹkunrẹrẹ, ọ le kan sí àwọn ọrẹ wa ni orí ẹ̀rọ ayélujára www.womenonweb.org tabi ki ọ lọ sí apá profili orilẹ-ede wa láti lè mọ nipa awọn èròjà oyún sise ni ìlú rẹ.
Àwọn Itọkasi:
Òògùn ìsẹ́yún kò ní ewu rárá, ọ sí tún dára tí a bá lò ó dáadáa. Oyún tí a lo mifopristone tàbí misoprostol máa sisẹ́ ni igba 95 tí a bá lò ó, tí àwọn ìdojúkọ rẹ̀ sí kéré ju ìdá igba 1 fún oyún ọsẹ nínú 10 ati idà 3 fún oyún ọsẹ 10 sí 13. Tí a bá lo misoprostol nikan, ọ ma n sise to igba 80 tabi 85 pẹlú ìdojúkọ igba ẹyọ kan 1 sí 4 fún oyún ọsẹ 13. Gẹgẹ bí àwọn àjọ onímọ̀ ìjìnlè ti Agbaye lórí eto ìlera World Health Organization, oyún ṣíṣẹ́ pẹ̀lú òògùn ma ń ṣíṣẹ́ pupọ ti kò sí mú ewu dání ní wọn ìgbà tí o bá dá a lò ni ilé ti ọ sí ni ànfàní láti ri àwọn àlàyé tí ó dá mú ṣẹ lórí rẹ pẹlú àwọn òògùn òní iyebíye.
Àwọn Itọkasi:
Oríṣi òògùn ìṣẹ́yún méjì ni ó wà, tí ọ̀kọ̀ọ̀kan sì ń ṣiṣẹ́ ní ìlànà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀. Mifepristone máa ń dá ìpèsè hòmóònù tí ó máa ń mú oyún dàgbà dúró. Àwọn èròjà inú misoprostol sì máa ń ṣí àti de ẹnu ọ̀nà ilé ọmọ ní sísẹ̀ntẹ̀lé, a sì máa fún ilé ọmọ pọ̀, èyí tí yóò ti oyún náà jáde.
Misoprostol máa ń fún ilé ọmọ pọ̀ tí oyún náà yóò fi jáde.
Mifepristone máa ń dènà hòmóònù tí ó máa ń jẹ́ kí oyún dàgbà.
Bẹ́ẹ̀ni, o lè lo misoprostol nílé láìsí ewu. Tí o bá lò ó, gbìyànjú kí o wà níbi tí èrò kò pọ̀ sí (bí ilé rẹ) tí o sì lè fẹ̀gbẹ́ lélẹ̀ fún wákàtí díẹ̀ lẹ́yìn tí o bá lò ó tán. Yóò dára tí ẹnìkan bá wà pẹ̀lú rẹ tí ó lè tọ́jú rẹ, tí ò sì lè po tíì gbígbóná tàbí bá ọ wá nǹkan láti jẹ.