Òògùn ìséyún ní ìlànà ìlera ní agbègbè àwon tí ó ń ran omoníyàn lówó

Èkó orí èro ayélujára yìí ni a ti sètò láti fi kún ìmò nípa àti bí a se lè ní ètó sí ìséyún ní ìlànà ìlera (tàbí ògùn ìséyún) ní agbègbè àwon tí ó ń ran omoníyàn lówó. Èkó yìí ni a pèsè pèlú àjosepò láàrín ilé isé Medicins Sans Frontieres àti HowToUseAbortionPill.org Nípa ìmò tí íwo yíó kó nínú èkó yìí, wàá lè rii dájú wípé síséyún pèlu ógùn kò panilára, ó wà ní àrówótó, àti wípé ó wà títí. Èkó yìí ni a pèsè pèlú àjosepò láàrín ilé isé Médecins Sans Frontières àti www.HowToUseAbortionPill.org

HowToUseAbortionPill.org nÍ àjǫșepǫ pèlu ilé isé tí a kò dá sílè fún èrè, èyìtí ó wà ní orílé ède Améríkà.
HowToUseAbortionPill.org ń se wà fún ìmò nìkan, won kò ní àjosepò pèlú ilé isé ìlera rárá.

    Women First Digital ló sagbátẹrù ẹ̀.